Jump to content

Donisia Minja

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

 

Donisia Minja
Personal information
OrúkọDonisia Daniel Minja
Ọjọ́ ìbíọjọ́ kẹsán Oṣù Kẹjọ ọdún 1999
Ibi ọjọ́ibíTanzania
Playing positioniwájú
Club information
Current clubYanga Princess
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
Yanga Princess
National team
Tanzania
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of 2 March 2022. † Appearances (Goals).

Donisia Daniel Minja tí a bí ní ọjọ́ kẹsán Oṣù Kẹjọ ọdún 1999 jẹ́ ogbóǹtarìgì agbábọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ̀-ède Tanzania tí ó ṣeré ipò iwájú lórí pápá fún Yanga Princess àti ẹgbẹ́ <a href="./Boolu-afesegba" rel="mw:WikiLink">agbábọ́ọ̀lù</a> obìnrin Tanzania .

Ní ọdún 2018, Minja mi àwọ̀n pẹ̀lú àmì ayò mẹ́ta ní bi ìdíje CECAFA Women’s Championship ti ọdún 2018 láti gba àmì ẹ̀yẹ ẹni tí ó mi àwọ̀n jùlọ ní bi ìdíje náà.

  • Asiwaju Awọn Obirin CECAFA : 2018
  • CECAFA Women ká asiwaju Top Scorer Ọdun 2018

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]