Donna Summer

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Donna Summer
Donna Summer in 2009
Donna Summer in 2009
Background information
Orúkọ àbísọLaDonna Adrian Gaines
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíiDonna Gaines
Ọjọ́ìbí(1948-12-31)Oṣù Kejìlá 31, 1948
Boston, Massachusetts, U.S.
AláìsíMay 17, 2012(2012-05-17) (ọmọ ọdún 63)
Naples, Florida, U.S.
Irú orinPop, disco, dance, rock, R&B
Occupation(s)Singer, songwriter
InstrumentsVocals, piano
Years active1968–2012
LabelsOasis, Casablanca (1975–80), Geffen (1980–88), Atlantic (1988–91), Mercury (1994–96), Warner-Elektra-Atlantic (1980–91), Epic (1999–2001), Burgundy (2006–12)
Associated actsGiorgio Moroder, Brooklyn Dreams

Donna Summer (oruko abiso LaDonna Adrian Gaines) (December 31, 1948 – May 17, 2012)[1] je akorin ati akoweorin ara Amerika to gbajumo nigba asiko disco ni opin ewadun 1970s. O gba Ebun Grammy ni emarun, Summer je olorin akoko to ni awo-orin meta to de ipo kinni ni Amerika lori atojo Billboard, be sini o tun ni orin merin ni ipo kinni larin osu 13.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. [[[:Àdàkọ:Allmusic]] allmusic ((( Donna Summer > Biography )))]