Doreen Nabwire

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Doreen Nabwire

Nabwire in Amsterdam in 2013
Personal information
OrúkọDoreen Nabwire Omondi
Ọjọ́ ìbí5 Oṣù Kẹta 1987 (1987-03-05) (ọmọ ọdún 37)
Ibi ọjọ́ibíKorogocho, Nairobi, Kenya
Ìga1.65m
Playing positionMidfielder
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
2002–2008Mathare United Women
2009–2010SV Werder Bremen (women)18(7)
2010–2011PEC Zwolle (women)16(1)
2011–2013Matuu FC(4)
2013–20141. FC Köln (women)1(0)
2013–20141. FC Köln II6(1)
National team
2001–2016Kenya women's national football team
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.
† Appearances (Goals).

Doreen Navwire jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini 5, óṣu march ni ọdun 1987. Arabinrin naa ṣere fun PEC Zwolle FC gẹgẹbi midfielder[1][2][3][4].

Àṣeyọri[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Doreen jẹ obinrin akọkọ ilẹ kenya lati ṣere bọọlu ni ilẹ europe. Arabinrin naa tun jẹ director awọn obinrin agbabọọlu fun federation bọọlu ilu kenya[5]

Itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. https://www.worldfootball.net/player_summary/doreen-nabwire/
  2. https://www.standardmedia.co.ke/sports/amp/Football/2001426651/former-harambee-starlets-captain-doreen-nabwire-lands-fifa-appointment
  3. https://nation.africa/kenya/sports/football/doreen-nabwire-appointed-to-fifa-advisory-group-3588540
  4. https://tisini.co.ke/2020/12/13/doreen-nabwire-exclusive-from-the-slums-to-stardom-in-europe/
  5. https://int.women.soccerway.com/players/doreen-nabwire-omondi/97945/