Dorothy Dandridge
Ìrísí
Dorothy Dandridge | |
---|---|
Dorothy Dandridge as "Mahia" in the trailer from the M-G-M thriller The Decks Ran Red (1958). | |
Ọjọ́ìbí | Dorothy Jean Dandridge Oṣù Kọkànlá 9, 1922 Cleveland, Ohio, USA |
Aláìsí | September 8, 1965 West Hollywood, California, USA | (ọmọ ọdún 42)
Cause of death | Embolism[1] or Overdose[2] |
Orúkọ míràn | Dorothy Dandridge-Nicholas Dorothy Nicholas Dorothy Dandridge-Denison Dorothy Denison |
Iṣẹ́ | Actress, singer |
Ìgbà iṣẹ́ | 1934–65 |
Olólùfẹ́ | Harold Nicholas (m. 1942–1951) Jack Denison (m. 1959–1962) |
Àwọn ọmọ | Harolyn Suzanne Nicholas |
Dorothy Jean Dandridge (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ Kẹ̀sán-án oṣù kọkànlá ọdún 1922 – ọjọ́ kẹjọ oṣù kẹsàn-án 1965) jẹ́ òṣeré-bìnrin àti akọrin ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà, òun sì ni ọmọ Adúláwọ̀-Amẹ́ríkà àkókò tí wọ́n dárúkọyàn fún Ẹ̀bùn Akádẹ́mì fún òṣèré-bìnrin tó dára jùlọ.[3]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Robinson, Louie (March 1966). "Dorothy Dandridge Hollywood's Tragic Enigma". Ebony. pp. 71. http://books.google.com/books?id=IjAJ7Wl1voUC&pg=PA70&#v=onepage&q&f=false. Retrieved 2012-09-10.
- ↑ Gorney, Cynthia (February 9, 1988). "The Fragile Flame of Dorothy Dandridge; Remembering the Shattered Life Of a Beautiful 1950s Movie Star". Washington Post. pp. E2.
- ↑ Potter, Joan (2002). African American Firsts: Famous Little-Known and Unsung Triumphs of Blacks in America. Kensington Books. pp. 81. ISBN 0-7582-0243-1.