Dorra Zarrouk
Dorra Zarrouk | |
---|---|
Dorra Zarrouk on the cover of Tunivisions, in January 2016 | |
Orúkọ àbísọ | درة زروق |
Ọjọ́ìbí | Dorra Ibrahim Zarrouk درة إبراهيم زروق 13 Oṣù Kínní 1980 Tunis, Tunisia |
Orílẹ̀-èdè | Tunisian, Egyptian |
Iṣẹ́ | Actress |
Ìgbà iṣẹ́ | 2002–present |
Olólùfẹ́ | Hany Saad (m. 2020) |
Dorra Ibrahim Zarrouk (Lárúbáwá: درة إبراهيم زروق, bíi ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kìíní ọdún 1980)[1] jẹ́ òṣèré lórílẹ̀-èdè Tunisia.[2][3][4][5]
Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Dorra sí ìlú Tunis. Bàbá rẹ̀ ni Ibrahim Zarrouk, bàbà ìyá rẹ̀ sì ni Ali Zouaoui tí ó jẹ́ òṣèlú.[6][7] Dorra gboyè nínú ìmò òfin àti òṣèlú láti ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Saint Joseph University ní Lebanon ní ọdún 2003.[8][9][10]
Iṣẹ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Dorra bẹ̀rẹ̀ eré ṣíṣe ní ọdún 1997.[11] Ní ọdún 2020, ó kópa nínú eré Khorma.[12] Ní ọdún 2003, ó farahàn nínú eré Colosseum: Rome's Arena of Death[13]. Eré orí tẹlẹfíṣọ̀nù tí ó má kọ́kọ́ ṣé ni orílẹ̀ èdè mìíràn yàtọ̀ sí Tunisia ni Fares Bani Marwan ní orílẹ̀ èdè Syria ní ọdún 2004. Lára àwọn eré tí ó tí ṣe ni Al Mosafer, Tisbah Ala Khair àti Sheikh Jackson.[14][15]
Ìgbésí ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Dorra fẹ́ Qays Muktar ní ọdún 2012.[16] Ní ọdún 2020, ó ṣe ìgbéyàwó pelu Hany Saad.[17][18]
Àwọn Ìtọ́kàsi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Dorra Zarrouk". BodySize.org (in Èdè Faransé). Retrieved 2020-08-24.
- ↑ "Dorra Zarrouk". africultures.com (in Èdè Faransé). Retrieved 19 January 2020.
- ↑ "Dorra Zarrouk". jeuneafrique.com (in Èdè Faransé). Mohamed Habib Ladjimi. Retrieved 19 January 2020.
- ↑ "Dorra Zarrouk Prix de la meilleure actrice au Festival " Nejm El Arab " du Caire". realites.com.tn (in Èdè Faransé). Retrieved 19 January 2020.
- ↑ "الفنانة درة تأخذنا في جولة داخل حياتها الخاصة لأول مرة Dorra Zarrouk". youtube (in Èdè Árábìkì). Alghad TV - قناة الغد. Retrieved 19 January 2020.
- ↑ "Tout en poursuivant de brillantes études, cette jeune comédienne est devenue la coqueluche des téléspectateurs tunisiens". jeuneafrique.com (in French). 24 January 2005.
- ↑ "درة في ضيافة "بوابة الأهرام": أحلم بالمسرح الاستعراضي وإعادة فوازير رمضان". ahram.org (in Arabic). 13 June 2018.
- ↑ "درة التونسية تفتخر بدور "العاهرة".. ولهذا السبب لم تتزوج بعد". elfann.com (in Arabic). 21 February 2018.
- ↑ "درة زروق للحصري : "رغم هجرتي إلى مصر أبقى درّة التونسية.... و بلبنان كنت أزور باستمرار صبرا وشتيلا...."". espacemanager.com (in Arabic). 19 November 2012.
- ↑ "There’s Something About Dorra Zarrouk You Don’t Know…". vogue.me. 15 January 2018.
- ↑ "Dorra Zarrouk". africultures.com (in French).
- ↑ "Our exclusive interview with Tunisian actress Dorra Zarrouk". emirateswoman.com. 30 November 2018.
- ↑ "Our list of top 20 Arab social media stars". stepfeed.com. 30 June 2017.
- ↑ "Dorra Zarrouk: The Scintillating star bids farewell to summer". insight-egypt.com. 15 October 2017. Archived from the original on 30 October 2020. Retrieved 29 November 2020.
- ↑ "In Conversation With: The Arab Film World's Most In-Demand Actress". harpersbazaararabia.com. 10 January 2019.
- ↑ "In Conversation With: The Arab Film World's Most In-Demand Actress". harpersbazaararabia.com. 10 January 2019.
- ↑ "ما حقيقة ارتباط درة برجل الأعمال هاني سعد؟". ET بالعربي (in Arabic). 20 April 2020.
- ↑ "حقيقة زواج درة و هاني سعد رجل الاعمال". البريمو نيوز (in Arabic). 27 October 2020.