Droëwors
Ìrísí
A piece of droëwors / dry wors | |
Course | Sausage |
---|---|
Place of origin | Namibia, South Africa |
Main ingredients | Beef and mutton |
Àdàkọ:Wikibooks-inline
|
Droëwors ( /ˈdruːəvɔrs/; Afrikaans fún sọ́séèjì gbígbẹ ó jẹ́ oúnjẹ ìpanu ó jẹ́ oúnjẹ ìbílẹ̀ tí a ṣẹ̀dá pẹ̀sú kóró èso cọriáńdà tí a fi pa sọséèjì. [1] A sábà máa ń se é bíi dunwors (Afrikaans fún "sọséèjì tín-ín-rín") dípò dikwors ("sọ́séèjì tó ki"), gẹ́gẹ́ bíi sọséèjì tín-ín-rín ṣe máa ń tètè gbẹ, bẹ́ẹ̀ náà ni kìí tètè bàjẹ́ kí wọ́n tó fi pamọ́. Tí wọ́n bá lo dikwors , wọ́n á tẹ́ẹ pẹrẹsẹ kó baà le tètè gbẹ.
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Garbee, Jenn (January 7, 2009). "Beverly Hills meat shop specializes in worldly tastes". The Los Angeles Times. https://www.latimes.com/style/la-fo-jerky7-2009jan07-story.html.