Dumebi Agbakoba

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àwòrán Dumebi níbi ayẹyẹ kan

Dumebi Agbakoba tí àwọn ènìyàn mọ̀ sí Chef Dish jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Naijiria. Iṣẹ́ alásè ni ó yàn láàyò. Òun sì ni olùdarí Samantha Lifestyle Group.[1]


Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Online, Tribune (2017-11-25). "I traded being a home cook for professional chef - Dumebi, Olisah Agbakoba’s daughter". Tribune Online. Retrieved 2022-07-07.