Dumfries

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Dumfries jẹ́ ọjà àárín ìlú, ó sì fìgbà kan jẹ́ ọjà fún àwọn ọlọ́lá àti lọ́balọ́ba ní Dumfries àti Galloway, ní Scotland, lẹ́bàá etí odò Nith.[1]

Saájú kó tó di ọba Scots, Robert the Bruce pa orogún rẹ̀, ìyẹn Red Comyn ní Greyfriars Kirk, ní ìlú ní ọdún 1306. Young Pretender ní ilé-iṣẹ́ rè ní agbègbè náà títí wọ òpin ọdún 1745. Nínú Ogun Agbaye Keji, àwọn ọmọ-ológun ti ìlú Norweg tó wà lẹ́yìn odi, ní Britain ló pọ̀jù nínú àwọn ọmọ-ológun Dumfries.

Ìtàn[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Kò sí àlàyé rere nípa ìlú yìí, láti ìgbà tí wọ́n ti tẹ̀ ẹ́ dó.[2]

Díẹ̀ nínú àwọn òǹkọ̀wé kan gbà pé Dumfries gbilẹ̀ bí àyè ìyàtọ̀ lákòókò iṣé Roman ti apá Àríwá ilẹ̀ Britain.[3]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. John Thomson's Atlas of Scotland, 1832 from National Library of Scotland Retrieved 3 June 2013
  2. "History of the Burgh of Dumfries – Chapter I". Electricscotland.com. Retrieved 24 August 2011. 
  3. "History of the Burgh of Dumfries – Chapter I". Electricscotland.com. Retrieved 24 August 2011.