Duro Onabule

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Duro Onabule (27 September 1939 – 16 August 2022) jẹ́ akoroyin ọmọ Nigeria, Tí ó jé olootu fún National Concord láti ọdún 1984 sí ọdún 1985,lẹ́yìn náà o di...

Ìgbésíayé àti ise re[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A bí Onabule ní ọdún 27 September 1939 ní Ìjẹ̀bú- òde , Ó jáde ilé ìwé CMS Grammar School àti ilé ìwé Journalism, London. Isẹ àkọ́kọ́ rẹ jẹ́ isẹ ajábò ìròyìn fún Daily Express ní ọdún 1961; Lẹ́yìn ọdún mẹ́ta ó dára pò mọ staff of the Daily Sketch. Ó lo ọdún díẹ̀ pẹ̀lú the Daily Sketch kí ó tó padà sí isẹ rẹ àkọ́kọ́ the Daily Express.[1]Ní ọdún 1969,ó sise gege bí London correspondent for the Daily Express. Ní mid 1970s, Ó sise fún the Daily Times, o ń dìde bò láti jẹ igbá kejì olootu fún Headlines magazine nígbàtí MKO Abiola béèrè Concord Press, wó yan Onabule gẹ́gẹ́ bí olootu ní ọdún 1984, Lẹ́yìn náà ó di olootu National Concord.[2]

Onabule kú ní ọdún 16 August 2022 ní ọmọ ọdún 82.[3].

Àwọn itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Udo, Mary (6 March 2017). "ONABULE, Chief Duro". Biographical Legacy and Research Foundation (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 1 July 2018. 
  2. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named dayo
  3. "Veteran journalist, Duro Onabule, dies at 83". 17 August 2022. https://punchng.com/veteran-journalist-duro-onabule-dies-at-83/.