ESB Villeneuve-d'Ascq

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Olayinka Sanni.

ESB Villeneuve-d'Ascq ni egbe agbaboolu alapere to budo si Villeneuve d'Ascq, ni Fránsì. Ìdásílẹ̀ 1987, arena Le Palacium.

Olayinka Sanni (ojoibi 1986) je agbaboolu alapere ara Nàìjíríà to un gba ipo iwaju alagbara fun ESB Villeneuve d'Ascq.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]