Earl F. Hilliard
Ìrísí
Earl F. Hilliard jẹ́ ẹni tí a bí ní ọjọ́ kẹsàn-án oṣù kẹrin ọdún 1942, ó jẹ́ Òṣèlú ní ilẹ̀ Amẹ́ríkà láti orílè-èdè U.S. Alabama tó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí Igbá-kejì rẹ̀, ní ìgbèríko keje ni Ìpínlẹ̀ orílè-èdè Amẹ́ríkà. [1]
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]A bí Hilliard ní Birmingham, Alabama, ó sì kàwé gboyè ní ilé ìwé Morehouse College.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Earl Frederick Hilliard". house.gov. Retrieved November 16, 2017.