Eben (olórin)
Ìrísí
Eben | |
---|---|
Orúkọ àbísọ | Emmanuel Benjamin |
Ọjọ́ìbí | 9 Oṣù Kẹ̀sán 1979 Lagos, Nigeria |
Irú orin |
|
Occupation(s) |
|
Years active | 2005–present |
Labels | Hammer House of Rock |
Associated acts | Jahdiel, Sammie Okposo, Onyeka Nwenu, Sonny Nneji, MI, Keffi |
Emmanuel Benjamin (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹsàn-án oṣù Kẹsàn-án ọdún 1979), tí ọ̀pọ̀ ènìyàn mọ̀ sí Eben jẹ́ olórin ẹ̀mí ní orílè-èdè Nàìjíríà, olóhùn dídùn àti òǹkọ-orin.[1]
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé atí ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Eben sí ìlú Eko, ní Nàìjíríà, ó jẹ́ ọmọ karùn-ún nínú àwọn ọmọ mẹ́fà tí àwn òbí rẹ̀ bí. Ó wá láti ìdílé onígbàgbọ́, ó sì lọ sí ilé-ìwé Orile Primary School, àti Community Grammar School, Orile, ní Ìpínlẹ̀ Èkó.[2]
Iṣẹ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní ọdún 1997, Eben bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ orin kíkọ lábẹ́ ìṣàkóso ẹ̀gbọ́nkùnrin gẹ́gẹ́ bí i olórin tàkasúfẹ̀ẹ́, àmọ́ ó yí padal sí kíkọ orin ẹ̀mí. Ní ọdún 2005, Eben di gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́ bí olórin ẹ̀mí lẹ́yìn tó kọ orin "Imarama" níbi àpéjọ àwọn ọ̀dọ́ èyí tí Pastor Chris gbé kalẹ̀.
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Eben". ALL MUSIC. Retrieved 20 October 2019.
- ↑ "Eben's Biography – Everything You Need To Know About Eben". Concise News. Retrieved 20 October 2019.