Eberechi Opara
Ìrísí
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | 6 Oṣù Kẹta 1976 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Nigeria | ||
Playing position | Defender | ||
National team | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
2000 | Nigeria women's national football team | ||
† Appearances (Goals). |
Eberechi Opara jẹ́ obìnrin agbábọ́ọ̀lù ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹfà oṣù kẹta, ọdún 1976. Agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi defender fun team apapọ awọn obinrin ilẹ naigiria lori bọọlu[1][2][3][4].
Àṣeyọri
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Eberechi kopa ninu Cup FIFA awọn obinrin agbaye ati ere idije olympic[5].