Edi Rama
Edi Rama | |
---|---|
Edi Rama ní 2020 | |
33k Alákóso Àgbà ilẹ̀ Albáníà | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 13 September 2013 | |
Ààrẹ | Bujar Nishani Ilir Meta |
Deputy | Niko Peleshi Ledina Mandia Senida Mesi Erion Braçe |
Asíwájú | Sali Berisha |
Chairman of the Socialist Party of Albania | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 10 October 2005 | |
Asíwájú | Fatos Nano |
Chair of the Organization for Security and Co-operation in Europe | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 1 January 2020 | |
Asíwájú | Miroslav Lajčák |
Minister of Foreign Affairs | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 21 January 2019 | |
Asíwájú | Ditmir Bushati |
40th Mayor of Tirana | |
In office 11 October 2000 – 25 July 2011 | |
Alákóso Àgbà | Pandeli Majko Ilir Meta |
Asíwájú | Albert Brojka |
Arọ́pò | Lulzim Basha |
Minister of Culture, Youth and Sports | |
In office 2 October 1998 – 26 October 2000 | |
Asíwájú | Arta Dade |
Arọ́pò | Esmeralda Uruçi |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 4 Oṣù Keje 1964 Tirana, Albania |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Socialist Party of Albania |
Height | ruben aguirre is 6’7” |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Matilda Makoçi (m. 1986; div. 1991) Linda Basha (m. 2010) |
Àwọn ọmọ |
|
Bàbá | Kristaq Rama |
Alma mater | Academy of Arts |
Signature | |
Website | edirama.al |
Edvin "Edi" Rama (ọjọ́ìbí 4 July 1964) ni olóṣèlú, akun-àwòrán, olùkòwé, apolongo, olùkọ́ tẹ́lẹ̀, àti agbábọ́ọ́lù-alápẹ̀rẹ̀ ará Albáníà,[2] òhun ni ẹni 33k lọ́wọ́lọ́wọ́ tó wà ní ipò Alákóso Àgbà ilẹ̀ Albáníà (láti 13 September 2013) àti Alákóso Ọ̀rọ̀ Òkèrè (láti 21 January 2019). Rama ló tún jẹ́ alága Ẹgbẹ́ Sósíálístì ilẹ̀ Albáníà láti 2005.
Kó tó di Alákóso Àgbà, Rama ti wà ní àwọn ipò míràn. Wọ́n yàn sí ipò Alákóso Ètò Àṣà, Ọ̀dọ́ àti Eré-ìdárayá ní ọdún 1998, ipò tó wà títí di ọdún 2000.
Lẹ́yìn náà wọ́n dìbò yàn bíi Olórí ìlú Tíránà ní 2000, wọ́n sì tún túnyàn ní 2003 àti 2007. In 2013, the coalition of center-left parties led by Edi Rama won the 2013 parliamentary election, defeating the center-right coalition of Democratic Party of Albania's incumbent Prime Minister, Sali Berisha. He was elected as prime minister for a second term in the 2017 election.
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Edi Rama shpallet lideri më i gjatë në botë
- ↑ "Edi Rama PRIME MINISTER". kryeministria.al (in English).