Edirne
Appearance
Edirne Adrianopolis | |
---|---|
Country | Turkey |
Regions | Marmara |
Province | Edirne |
District | Edirne |
Founded | 125 BC |
Founded by | Hadrian |
City Capital | Edirne |
Districts | |
Government | |
• Mayor | Recep Gürkan (CHP) |
• Governor | Dursun Ali Şahin |
Elevation | 42 m (138 ft) |
Population (2019) | |
• Total | 165.979 |
• Estimate (2019) | 400,280 |
• Density | 844/km2 (2,190/sq mi) |
Time zone | UTC+2 (EUT) |
• Summer (DST) | UTC+3 (EUST) |
Postal code | 22000 |
Area code | (+90) 284 |
ISO 3166 code | TR-22 |
Vehicle registration | 22 |
ISO 3166-2 | TR-22 |
Website | www.edirne.bel.tr |
Edirne je ilu ni Ariwa iwo oorun orile-ede Turki. Ni bi odun 16 century ni Mosalasi Selimiye di kiko lati owo ayaworan ile kiko, Mimar Sinah. Awon ohun ona ati ti eso ti orileede naa ati ti musulumi je ohun afihan fun gbogbo eniyan eleyi ti o ti bere lati isejoba Ottoman. Mosalasi Uç Serefeli eleyi ti kiko re waye lati odun 15th century, fi egbe tii ile iko ohun ona si yi.
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |