Jump to content

Editan

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ọbẹ̀ Editan

Ọbẹ̀ Editan jẹ́ ọbẹ̀ ẹ̀fọ́ vegetable soup tí ó ṣẹ̀ wá láti ọ̀dọ̀ àwọn èèyàn Efik People ti Cross River State ní Gúsù Gúsù Nigeria. Ó jẹ́ gbajúgbajà láàárín àwọn ènìyàn ìpínlẹ̀ Cross River . Ọbẹ̀ náà jẹ́ ṣíṣè láti ara ewé Editan, ewé tí ó korò. Síwájú kí ó tó di ṣíṣè ìkorò náà gbọ́dọ̀ di fífún jáde.[1][2][3]

Ewé Editan ní àwọn ènìyàn gbàgbọ́ pé a lè lò gẹ́gẹ́ bí àgbo.

[4]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Esema, Joseph D. (2002-01-01) (in en). Culture, customs, and traditions of Cross River State people of Nigeria. MOCOMP. https://books.google.com/books?id=nZIuAQAAIAAJ&q=Editan+soup. 
  2. Thaker, Aruna; Barton, Arlene (2012-04-23) (in en). Multicultural Handbook of Food, Nutrition and Dietetics. John Wiley & Sons. ISBN 9781405173582. https://books.google.com/books?id=YF1YCg5Ig-EC&q=Editan+soup&pg=PA256. 
  3. Uyanga, Roseline E. (1998-01-01) (in en). Briefs on Nigeria's indigenous and Western education: an interpretative history. Hall of Fame Educational Publishers. ISBN 9789783073227. https://books.google.com/books?id=QbQlAQAAIAAJ&q=Editan+soup. 
  4. oyibougbo (2022-06-20). "How To Make Editan Soup". Ou Travel and Tour (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-06-14.