Edith Eluma
Ìrísí
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | 27 Oṣù Kẹ̀sán 1958 | ||
Playing position | Defender | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
Princess Jegede | |||
National team‡ | |||
Nigeria women's national football team | |||
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Edith Eluma jẹ ọkan lara agbabọọlu lobinrin ti a bini 27, óṣu September ni ọdun 1958. Arabinrin naa ṣere fun team awọn obinrin naigiria ti national lori bọọlu[1][2].
Àṣèyọri
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Arabinrin na kopa ninu Cup FIFA awọn obinrin agbaye ni ọdun 1991 atipe ó ṣere ni ipo club fun princess jegede ni órilẹ ede Naigiria[3][4].