Edwin Muir

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Edwin Muir (15 May 18873 January, 1959) A bí Muir ní 1887. Ó kú ní 1959. Akéwì pàtàkì ni. Orkney ni Muir ti ṣe kékeré. Ní 1901 sí 1902 ni ó tẹ̀lé àwọn òbí rẹ̀ lọ sí Glasgow. Kò pẹ́ tí wọ́n dé Glasgow tí bí babá, ìyá àti àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ̀ méjì kú. Kò tíì ju ọmọ ọdún méjìdínlógún lọ lásìkò yìí káńsà (cancer) ni ó pa ìyá rẹ̀. Ikọ́ọfe (T.B) ni ó pa àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ. Nígbà tí ó ku òun nìkan, ó bẹ̀rẹ̀ sí níí ṣe iṣẹ́ akọ̀wé ní Glasgow. Ó kọ ọ̀pọ̀lọpọ̀ ewì.