Edwin Hubble
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Edwin Powell Hubble)
Edwin Powell Hubble | |
---|---|
Ìbí | Marshfield, Missouri, U.S. | Oṣù Kọkànlá 20, 1889
Aláìsí | September 28, 1953 San Marino, California | (ọmọ ọdún 63)
Ibùgbé | United States |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | American |
Pápá | Astronomy |
Ilé-ẹ̀kọ́ | University of Chicago Mount Wilson Observatory |
Ibi ẹ̀kọ́ | University of Chicago University of Oxford |
Ó gbajúmọ̀ fún | Big Bang Hubble's law Redshift Hubble sequence |
Influenced | Allan Sandage |
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́sí | Bruce Medal 1938 |
Edwin Powell Hubble (November 20, 1889 – September 28, 1953) je atorawo ara Amerika to se alaye bi agbalaaye se ri nipa sisafihan pe awon galaksi miran na wa leyin Galaksi Milky Way wa. Bakanna o tun sawari pe iyi "isele Doppler" (ni pato "redshift") to je kikiyesi ninu light spectra lati awon galaksi miran unposi ni iye si bi galaksi pato kan se jinnasi lati Aye. Ibasepo yi lo unje ofin Hubble, o si fihan pe agbalaaye unfesi.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |