Èdè Efik
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Efik language)
| Efik | |
|---|---|
| Efik (proper) | |
| Sísọ ní | Apágúúsù Nàìjíríà |
| Ọjọ́ ìdásílẹ̀ | 1998 |
| Agbègbè | Ìpínlẹ̀ Cross River |
| Ẹ̀yà | Efik |
| Ìye àwọn afisọ̀rọ̀ | 400,000 |
| Èdè ìbátan | |
| Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè | |
| ISO 639-3 | efi |
Efik tàbí Riverain Ibibio[1] jẹ́ èdè ní Nàìjíríà (ní Ìpínlẹ̀ Cross River).

Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Okon E. Essien, 1986, Ibibio names: their structure and their meanings