Egbé Akómolédè
Ìrísí
Ẹgbẹ́ Akọ́mọlédè àti àṣà Yorùbá jẹ́ àgbárí-jọ-pọ Àwọn olùkọ́ nílé ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀, girama àti ilé ẹ̀kọ́ fásitì ti ìjọba pẹ̀lú aládàáni jákè jádò ilẹ̀ Nàjíríà. Ẹgbẹ́ yìí ń ṣojú Yorùbá níbi ìgbé lárugẹ èdè, àṣà àti ìdàgbà sókè ìṣèṣe Yorùbá [1][2][3]
Àwọn ìtọ́ka sí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Egbe Akomolede ati Asa Naijiria". Archived from the original on 27 August 2018. Retrieved 30 October 2018.
- ↑ "Yoruba, a Must for All – Egbe Akomolede – Radio Nigeria Ibadan". Radio Nigeria Ibadan – Radio Nigeria Ibadan. Uplifting the people and uniting the Nation. (in Èdè Ruwanda). 2018-08-07. Retrieved 2018-11-01.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ admin (2018-07-26). "Latest news about Egbe Akomolede from Nigeria & world". TODAY.NG. Retrieved 2018-11-01.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |