Ego Ihenacho

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Ego Ihenacho Ogbaro je olorin ara Naijiria. o korin leyin Bisade ologunde( Lagbaja) fun odun mewa. Omo bibi ipinle Imo ni. Lo si ile iwe alakobere sentira ati ile iwe giga prestigiuos Ikeja ni ilu Eko.oO gbe igba orin re ni 2007 ti egbe re n je Indigo.O para po sise pelu Sunny Nneji, Tosin Martins, Ayanbirin, ASa ati bebelo. Akoko orin re ni Mo Gbagbo.O gba ami eye Kim Lawani ni 1998 (Most Promising Female Act of the Year) ati ami eye obirin olohun iyo ni 2006.

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]