Ejegayehu Dibaba

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ejegayehu Dibaba
Òrọ̀ ẹni
Orúkọ ìbílẹ̀Ijigaayoo Dibaabaa
Orúkọ àbísọእጅጋዬሁ ዲባባ
Ọjọ́ìbíOṣù Kẹta 21, 1982 (1982-03-21) (ọmọ ọdún 42)
Bekoji, Arsi Province, Derg
Sport
Orílẹ̀-èdèEthiopia
Erẹ́ìdárayáSport of athletics
Event(s)Long-distance running

Ejegayehu Dibaba Keneni ni a bini ọjọ kọkan leelogun, óṣu March, ọdun 1982 si Bekoji jẹ elere sisa lóbinrin ilẹ Ethiopia[1][2].

Àṣèyọri[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ni ọdun 2003, Dibaba kopa ninu ere ti gbogbo ilẹ Afirica ti mita ti ẹgbẹrun mẹwa to si gba ami ẹyẹ ti ọla ti wura[3]. Ni ọdun 2004, Ejegayehu kopa ninu Olympics ti Athens ninu mita ti ẹgbẹẹrun mẹwa to si gba ami ẹyẹ ti ọla ti silver[4]. Ni ọdun 2005, Dibaba kopa ninu idije agbaye lori ere sisa ti mita ti ẹgbẹrun maarun to si gba ami ẹyẹ ti ọla ti idẹ[5]. Ni ọdun 2010, Dibaba kopa ninu ere sisa ti kilo mita meje to wayr ni Memorial ti Peppe Greco to si gbe ipo keji. Ni ọdun 2011, Ejegayehu kopa ninu Marathon ti Chicago pẹlu wakati 2:22:09[6].

Itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Ejegayehu Player Profile
  2. Ejegayehu Dibaba
  3. All Africa Games
  4. 2004 Athens Games
  5. Bronze Medal
  6. Chicago Marathon