Iṣẹ́ẹ̀rọ oníná
Iṣẹ́ẹ̀rọ oníná tabi iṣẹ́ẹ̀rọ ìṣiṣẹ́oníná (Electronics engineering tabi electronic engineering lede Geesi), ni papa eko iseero nibi ti awon ohuninu onitanna alaije onigboro (non-linear) ati agbese bi awon igo elektroni, ati awon ero-imulo agbanasaradie, agaga awon tiransisto, adiojuona ati asoyipo olodidi, se unje mimulo lati seto awon asoyipo onina, ero-imulo ati sistemu, eyi tun je mo nipa awon ohuninu onitanna onirele, won si da lori awon patako asoyipo àtẹ̀kọ. Opo papa eko iseero to se pataki bi isiseonina alapinse, isiseonina eleyoika, ero onina, awon sistemu afisinu ati isiseonina agbara. Iseero isiseonina da lori igbese awon imulo, awon opo ilana ati algoritimu to jade ninu opo awon papa eko to ba laramu, fun apere isiseeda ipo alaralile, iseero redio, ibanisoroelero, awon sistemu ikojannu, igbese amioloro, iseero awon sistemu, iseero komputa, iseero iserinse, ikojannu agbara itanna, isiseroboti, ati opo awon miran.[1]
Instituti àwon Oniseero Onitanna ati Isiseonina (IEEE) ni ikan ninu awon agbajo to se patijulo ati to ni ipa julo fun awon oniseero isiseonina.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Brett Wilson/Z. Ghassemloooy/I. Darwazeh Analogue Optical Fibre Communications, p. xvi, Institution of Electrical Engineers, 1995 ISBN 978-0-85296-832-1