Iṣẹ́ẹ̀rọ onítanná

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àwọn oníṣẹ́ẹ̀rọ onítanná úndá àwọn sístẹ́mù agbára aṣòro...
...àti àwọn àsoyípo oníná.

Iṣẹ́ẹ̀rọ onítanná (Electrical engineering) ni papa eko iseero to un da lori agbeka ati imulo itanna, isiseonina ati iseonigberingberin onina. Papa eko yi koko di ise sise ni opin orundun okandinlogun leyin isodidunadura telegrafu itanna ati ipese agbara onitanna. Loni o ti de oro bi agbara, isiseonina, awon sistemu ijannu, igbese alamioro ati awon ibanisoroelero.

Iseero onitanna le tun je mo iseero onina. Iseero onitanna je gbigba pe o da lori awon isoro to je mo awon sistemu onitanna gbangba bi ifiranse agbara itanna ati ikojannu oko, nigbati iseero onina da lori agbeka awon sistemu onina kekere bi komputa ati awon asoyipo olodidi.[1] Tabi, a le so pe awon oniseero onitanna unda ise won lori lilo itanna lati fi safiranse okun onitanna, nigbati awon oniseero onina unda ise won lori lilo itanna lati se igbese aroye. Loni, ko fi be si iyato larin awon mejeji nitori idagbasoke to ti ba isiseonina agbara.


Ẹ tún wo[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "What is the difference between electrical and electronic engineering?". FAQs - Studying Electrical Engineering. Retrieved 20 March 2012. 

Ajapo ode[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àdàkọ:Wikibooks Àdàkọ:WVD Àdàkọ:Wikiversity