Jump to content

Elijah Abina

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Elijah Oludele Abina
Ọjọ́ìbí16 Oṣù Kẹfà 1935 (1935-06-16) (ọmọ ọdún 89)
Aradagun, Badagry Ipinle Eko Nàìjíríà
Orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Orúkọ mírànPapa Abina or Pastor Abina or Daddy GO
Iṣẹ́Clergyman
Olólùfẹ́
Matron Felicia Abina (nee Akinremi) (m. 1961)

Elijah Oludele Abina(bi i Okudu 16, 1935) je pasito ati Agba Aguntan ti The Gospel Faith Mission International (GOFAMINT).[1]

Elijah Ogundele Abina ti wo bi sinu ile Pa Abraham Akowanu Abina ni Aradagun, Badagry Ipinle Eko[2]

Pastor Abina gbe Felicia Abina ni iyawo ni Osu Keta Ojo 30, Odun 1966. Papo, won ni omo mefa, ti won je Folorunsho, Olabisi, Funmilayo, Ebunoluwa, Gbenga ati Femi. Matron Felicia Abina ku ni Osu Kefa Odun 2014.[3][4]

  1. "Why Nigeria has not disintegrated, by Pastor Abina, PFN founding father". Vanguard News. 2016-10-09. Retrieved 2022-02-25. 
  2. International, The Gospel Faith Mission. "Our Story – The Gospel Faith Mission International" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-01-15. 
  3. Okonoboh, Rita (2017-07-30). "We have lived together too long to disintegrate —Pastor (Dr) Abina, General Overseer, GOFAMINT". Tribune Online. Retrieved 2022-02-25. 
  4. Odebiyi, Olatunde (2014-09-12). "Exit of a ‘virtuous’ woman". The Nation Newspaper. Retrieved 2022-02-25.