Elisabeti Kìnní Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì
Jump to navigation
Jump to search
Elizabeth Kìnní | |
---|---|
![]() | |
Elizabeth I , "Darnley Portrait", c. 1575 | |
Reign | 17 November 1558 – 24 March 1603 ( | ọdún 44 , ọjọ́ 127 )
Coronation | 15 January 1559 |
Predecessor | Mary I |
Successor | James I |
House | House of Tudor |
Father | Henry VIII |
Mother | Anne Boleyn |
Burial | Westminster Abbey |
Signature | ![]() |
Elizabeth Kìnní (Elizabeth I) (7 September 1533 – 24 March 1603) ni Ayaba to joba lori Ilegeesi ati Ayaba to joba lori ile Irelandi lati 17 November 1558 titi de ojo iku re. Won tun mo bi Ayaba Wundia (The Virgin Queen), Gloriana, tabi Ayaba Bess Enirere (Good Queen Bess), Elizabeth lo je oba karun ati to gbeyin lati Ebi Tudor.
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |