Elisabeti Kejì
(Àtúnjúwe láti Elizabeth II)
Elisabeti Keji | |
---|---|
![]() | |
Elizabeth II in 1959 | |
Reign | 6 February 1952 – 8 September 2022 ( ọdún 70 , ọjọ́ 214 ) |
Coronation | 2 June 1953 |
Predecessor | George VI |
Successor | Charles III |
Prime Ministers | See list |
Consort | Prince Philip, Duke of Edinburgh |
Issue | |
Charles III Anne, Princess Royal Prince Andrew, Duke of York Prince Edward, Duke of Edinburgh | |
Full name | |
Elizabeth Alexandra Mary | |
House | House of Windsor |
Father | George VI |
Mother | Elizabeth Bowes-Lyon |
Signature | Fáìlì:Elizabeth II Signature.svg |
Religion | Church of England & Church of Scotland |
Elisabeti Keji (abiso Elizabeth Alexandra Mary; 21 April 1926 - 8 September 2022) je ayaba oriite fun awon orile-ede meedogun(15)) ti won n pe ni Ile Ajoni: Canada, Australia, New Zealand, Jamaica, the Bahamas, Grenada, Papua New Guinea, the Solomon Islands, Tuvalu, Saint Lucia, Saint Vincent and the Grenadines, Belize, Antigua and Barbuda, and Saint Kitts and Nevis. [1] [2] Ìjoba rè, tí ó wà fún odún aadorin àti osù méje jé isejoba tí o gùn jù ni isejoba orílè-èdè Britain.
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Àwon Ìtókasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
- ↑ McBride, James (2021-11-16). "Queen Elizabeth II Is the Monarch of Fifteen Countries. What Does That Mean?". Council on Foreign Relations. Retrieved 2022-03-21.
- ↑ "Barbados becomes a republic and parts ways with the Queen". BBC News. 2021-11-30. Retrieved 2022-03-21.