Jump to content

Elizabeth Olsen

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Elizabeth Olsen
A photograph of Olsen speaking at the 2019 San Diego Comic-Con International
Olsen ní ọdún 2019
Ọjọ́ìbíElizabeth Chase Olsen
16 Oṣù Kejì 1989 (1989-02-16) (ọmọ ọdún 35)
Sherman Oaks, California, U.S.
Iléẹ̀kọ́ gígaNew York University
Iṣẹ́Actress
Ìgbà iṣẹ́1994–present
Olólùfẹ́Robbie Arnett
Àwọn olùbátan

Elizabeth Chase Olsen (tí a bí ní ọjọ́ kẹríndínlógún oṣù kejì ọdún 1989) jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Wọ́n bi ní Sherman Oaks, California, Olsen ti bẹ̀rẹ̀ ṣíṣe láti ìgbà tí ó ti jẹ́ ọmọ ọdún merin. Ó kópa nínú fíìmù fún ìgbà àkọ́kọ́ nínú fíìmù Martha Marcy May Marlene ní ọdún 2011, ó sì gba àmì-ẹ̀yẹ Critics' Choice Movie Award nítorí ipa rẹ̀ nínú fíìmù náà. Olsen tún padà gba àmì-ẹ̀yẹ BAFTA Rising Star AwardNew York University lẹ́yìn ọdún méjì.

Olsen gbajúmọ̀ káàkiri àgbáyé fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Wanda Maximoff / Scarlet Witch nínu àwọn fíìmù Marvel Cinematic Universe, ó wà nínú àwọn fíìmù bi Avengers: Age of Ultron (2015), Captain America: Civil War (2016), Avengers: Infinity War (2018), Avengers: Endgame (2019), àti Doctor Strange in the Multiverse of Madness (2022), pẹ̀lú pẹ̀lú WandaVision (2021).