Ellen Coleman
Ìrísí
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | 11 Oṣù Kejìlá 1995 | ||
Playing position | Defender | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
Lady Strikers | |||
National team‡ | |||
2017-18 | Ghana women's national football team | 2 | (0) |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Ellen Coleman jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini 11, óṣu December ni ọdun 1995. Agbabọọlu naa ṣere fun awọn ọdọmọbinrin strikers gẹgẹbi defender[1].
Àṣeyọri
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Ellen kopa ninu Cup awọn obinrin ilẹ afirica ti ọdun 2018[2].