Emmy Gee
Ìrísí
Emmy Gee | |
---|---|
Orúkọ àbísọ | Emmanuel Nwankwo[1] |
Ọjọ́ìbí | 10 Oṣù Kẹjọ 1986 Nigeria |
Ìbẹ̀rẹ̀ | Johannesburg, South Africa |
Irú orin | Hip hop |
Occupation(s) |
|
Years active | 2013–present |
Labels | Teamtalkless |
Associated acts |
|
Emmanuel Nwankwo, tí a tún mọ̀ sí Emmy Gee, jẹ́ olórin ilẹ̀ Nàìjíríà tó ń gbé ní orílẹ̀-èdè South Africa. Orin àdákọ àkọ́kọ́ rẹ̀ "Rands and Nairas" wà nípò keje láàárín àwọn orin orí àtẹ ní ilẹ̀ South Africa.[2] Ó bẹ̀rẹ̀ sí ní gba orin sílẹ̀ nígbà tó wà ní ọmọdún mẹ́rìndínlógún, ó sì í ṣiṣẹ́ pẹ̀lú Shizzi n ọdún 2004. Ó jùmọ̀ ṣe ìdásílẹ̀ ilé-iṣẹ́ kan, tí wọ́n ń ṣe ohun ìdánilárayá àti aṣọ tí a mọ̀ Teamtalkless.[1][3]
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ àti orin àkọ́kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Emmy Gee sí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, láti ẹ̀yà Ibo. Òun ni àbígbẹ̀yìn láàrin àwọn ọmọ mẹ́rin. Ó ṣe àṣeparí ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ àti girama ní Naijiria kí ó tó kó lọ sí ilẹ̀ South Africa. Wọ́n ṣe ìgbéjáde orin àdákọ alákọ̀ọ́kọ́ Emmy Gee "Rands and Nairas" ní ọdún 2013.
Àtòjọ orin rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Orin àdákọ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Title | Year | Peak chart positions | Album |
---|---|---|---|
SA | |||
"Rands and Nairas" (featuring AB Crazy and DJ Dimplez) |
2013 | 7 | TBA |
"Rands and Nairas (Remix)" (featuring Ice Prince, AB Crazy, Anatii, Phyno, Cassper Nyovest and DJ Dimplez) |
2014 | ||
"Champagne Showers" (featuring King Jay) |
2015 |
Gẹ́gẹ́ bíi àfifún olórin
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Artist | Title | Year | Peak chart positions | Album |
---|---|---|---|---|
SA | ||||
Buffalo Souljah | "Ziyawa" (featuring. Red Button & Emmy Gee) | 2014 | The Chosen One | |
Bolo J | "This Year" (featuring. Emmy Gee) | 2015 | Non-album singles | |
DJ Dimplez | "Bae Coupe" (featuring. Ice Prince, Emmy Gee & Riky Rick) | |||
DJ Scratch Masta | "To the Tope" (featuring. Emmy Gee, AB Crazy & Eindo) | 2016 | ||
King Jay | "Owami" (featuring. Emmy Gee) | |||
Tkinzy | "Shake Ikebe" (featuring. Emmy Gee) | |||
Teamtalkless | "Church" (featuring. DJ Dimplez, TRK, Emmy Gee & King Jay) [4] | 2017 | ||
DJ Kaywise | "Normal Level" (featuring. Ice Prince, Kly & Emmy Gee) | 2018 | Àdàkọ:TBA |
Àwọn àmì-ẹ̀yẹ̀ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Year | Awards ceremony | Award description(s) | Recipient | Results | Ref |
---|---|---|---|---|---|
2014 | Nigeria Entertainment Awards | Best Music Video of the Year (Artist & Director) | "Rands and Nairas" | Gbàá | [5] |
Diaspora Artist of the Year | Himself | Wọ́n pèé | [6] | ||
Channel O Music Video Awards | Most Gifted Newcomer | Wọ́n pèé | [7] | ||
Most Gifted Video of the Year | "Rands and Nairas" | Wọ́n pèé | |||
2015 | Nigeria Entertainment Awards | Diaspora Artist of the Year | "Himself" | Wọ́n pèé | [8] |
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 "EMMY GEE Biography". MTV Base. Archived from the original on 28 July 2014. Retrieved 26 July 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "AIRPLAY CHART". EMA. Archived from the original on 29 April 2014. Retrieved 26 July 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "EMMY GEE: SPENDING RANDS AND NAIRAS". Zalebs. Archived from the original on 26 July 2014. Retrieved 26 July 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Solanke, Abiola. "Teamtalkless "Church" ft DJ Dimplez, TRK, Emmy Gee, King Jay". Pulse Nigeria. Archived from the original on 19 August 2017. Retrieved 19 August 2017. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Nigerian Entertainment Awards; Full List of Winners". Daily Times of Nigeria. 1 September 2014. Archived from the original on 22 October 2014. Retrieved 2 September 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Abimboye, Micheal (31 May 2014). "Pop duo, Skuki, reject Nigerian Entertainment Awards nomination". Premium Times. Archived from the original on 5 June 2014. Retrieved 1 June 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Marshall, Rhodé (5 September 2014). "Channel O Africa announces Music Video Awards nominees". Mail & Guardian. Archived from the original on 13 September 2014. Retrieved 12 September 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Olayinka, Obey (7 September 2015). "See Moments From The 10th NEA Awards And List Of Winners [PICTURES]". Naij. Archived from the original on 21 August 2016. Retrieved 19 August 2017. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)