Jump to content

Ephraim Akpata

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àdàkọ:EngvarB

Ephraim Ibukun Akpata
Alága àkọ́kọ́ Independent National Electoral Commission
In office
1998 – January 2000
AsíwájúSumner Dagogo-Jack
Arọ́pòAbel Guobadia
Justice of Supreme Court
In office
1993 – Unknown
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí15 April 1927
Edo State
Aláìsí8 January 2000(2000-01-08) (ọmọ ọdún 72)
AráàlúNigerian

Ephraim Omorose Ibukun Akpata (wọ́n bí lọ́jọ́ 15 oṣù April ọdún 1927 – ọjọ́ 8 oṣù January ọdún 2000) jẹ́ Adájọ́-àgbà ilé-ẹjọ́ tó ga jù lọ Nigeria, Supreme Court of Nigeria àti alága àkọ́kọ́ tí Independent National Electoral Commission (INEC) ní Nigeria, òun ni ó ṣe ètò ìdìbò ọdún 1998/1999 tí wọ́n bí àtúnbẹ̀rẹ̀ ìjọba àwararawa ní Nigeria l'óṣù June ọdún 1999.[1]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Jude Opara (2 June 2009). "INEC 10 Years After – an Appraisal". Daily Champion. Retrieved 13 February 2010.