Jump to content

Sumner Dagogo-Jack

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Sumner Karibi Dagogo-Jack
Chairman of the National Electoral Commission of Nigeria
In office
1994–1998
AsíwájúOkon Uya
Arọ́pòEphraim Akpata
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí1930 (ọmọ ọdún 93–94)
Abonnema, Akuku-Toru LGA, Rivers State, Nigeria

olóyè Sumner Karibi Dagogo-Jack (wọ́n bí lọ́dún 1930) jẹ́ alága Àjọ elétò ìdìbò lorílẹ̀ èdè Nigeria, National Electoral Commission of Nigeria (NECON) tí ìjọba ológun ti Ààrẹ ìjọba ológun Sani Abacha yàn lọ́dún 1994 sí 1998.[1]

Dagogo-Jack jẹ́ ọ̀kan lára ìgbìmọ̀ àjọ ìdìbò tí Humphrey Nwosu dárí lọ́dún (1989 sí 1993), tí wọ́n sì wá yàn gẹ́gẹ́ bí alága àjọ ètò ìdìbò Nigeria lẹ́yìn náà.[2]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Imam Imam (9 June 2010). "Past INEC Chairmen". ThisDay. Retrieved 2010-06-10. 
  2. Muyiwa Oyinlola (2 May 2010). "From Esua to Iwu, who will rescue Nigeria?". Nigerian Compass. Retrieved 2010-06-10.