Jump to content

Esther Onyenezide

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

 

Esther Chinemerem Onyenezide (tí a bí ní ọjọ́ ogbọ̀n oṣù kẹfà ọdún 2003) ó jẹ́ agbábóòlù ti Nàìjíríà tí ó ń gbá bóòlù gẹ́gẹ́ bí midifira fún àwọn ẹgbẹ́ obìnrin Spanish Madrid CFF àti ẹgbẹ́ agbábóòlù orílè-èdè obìnrin Nàìjíríà .

Ní ọdun 2022, FIFA yàn gẹ́gẹ́ bí Oluṣere tí ó gbá ayọ̀ wọlé lẹ méjì nígbà ìgbà wọlé tí kánádà 3 - 1.

Ìgbésí ayé gbogbogbo

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Esther ṣe aṣojú fún Nàìjíríà ní ọdún 2022 FIFA U-20 World Cup ní Costa Rica, gbá bọ́ọ̀lù fún FC Robo Queens ṣáájú kí o to lọ sí Madrid CFF pẹ̀lú àdéhùn mẹ́ta ní 2024.