Etí

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Etí
HumanEar.jpg
Human (external) ear
Eti Eniyan

Etí jé èyà ará tí ènìyàn àti eranko fi ngbo òrò àti láti dúró déédé. Ènìyàn ati eran òsìn(tí oyinbo n pè ní "mammals") ni etí méjì. A lè pín etí sí èyà méta; etí ìta, etí àárín àti etí inú, awon èyà méta n sise papò láti mú kí ènìyàn tàbí eranko gbóro. Ìjàmbá sí eti(pàápa jù lo; ìlù etí) le fa aigboran tàbí ìsòro ní gbigboran.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]