Etenesh Diro
Ìrísí
Etenesh Diro, 2019 | |
Òrọ̀ ẹni | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 10 Oṣù Kàrún 1991 |
Height | 1.68 m (5 ft 6 in) |
Weight | 49kg |
Sport | |
Orílẹ̀-èdè | Ethiopia |
Erẹ́ìdárayá | Track and field |
Event(s) | 3000 metres steeplechase |
Etenesh Diro Neda ni a bini ọjọ kẹwa, óṣu May, Ọdun 1991 jẹ elere sisa lobinrin ti órilẹ ede Ethiopia[1][2].[3]
Aṣèyọri
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Etenesh kopa ninu olympics ti 2012 ati 2016 lori mita ti ẹgbẹrun mẹta ti steeplechase[4]. Ni ọdun 2012, Diro kopa ninu àṣekagba ere Olympic to waye ni London pẹlu ipo kẹfa pẹlu wakati 9:19.89[5]. Ni ọdun 2013, Diro kopa ninu idije agbaye ti mita ẹgbẹrun mẹta to si pari pẹlu ipo kaarun pẹlu wakati 9:16.97. Ni ọdun 2017, Etenesh kopa ninu idije agbaye ti London ti mita ẹgbẹrun mẹta to si pari pẹlu ipo keje pẹlu wakati 9:22.46.
Àwọn itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Diro Details
- ↑ Etenesh Diro Profile
- ↑ "Etenesh DIRO Biography, Olympic Medals, Records and Age". Olympics.com. 2018-06-27. Retrieved 2023-04-15.
- ↑ Steeplechase 3000m
- ↑ Olympics