Jump to content

Etido Ibekwe

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Etido Ibekwe jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó sì tún jẹ́ Aṣáájú ọmọ ẹgbẹ ti o pọ julọ nígbà kan rí ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ìpínlẹ̀ Akwa Ibom . O soju agbegbe Essien Udim ni Apejọ naa. [1] [2] [3]