Etso Ugbodaga-Ngu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Etso Ugbodaga-Ngu
Ọjọ́ìbíEtso Clara Ugbodaga-Ngu
Àdàkọ:Birth year
Kano
Aláìsí1996 (ọmọ ọdún 74–75)
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigeria
Ẹ̀kọ́Art teacher's diploma, National Diploma in Design
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity of London 55, Chelsea School of Art, London, 1954
Iṣẹ́Artist
Fáìlì:Beggars by Etso Ugbodaga-Ngu.jpg
Beggars (1963)

Etso Clara Ugbodaga-Ngu tí a tún mọ̀ sí Ugbodaga-Ngu, fìgbà kan jẹ́ oníṣẹ́-ọnà ọmọ-orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ọdún 1921 ní Kano, ní ipinle Kano ni wọ́n bi sí, ó si fi ipa rere sí ọ̀rọ̀ òṣèlú àti àṣà ní ilẹ̀ Nàìjíríà.[1][2] Iṣẹ́-ọnà rẹ̀ máa ń fi okùn hàn. Lára àwon iṣé rẹ̀ ni "Market Women" tí ọdún (1961).

Iṣẹ́ rẹ̀, ìyẹn "Dancers" ni Elbert G. Mathews, tó jẹ́ aṣojú ilẹ̀ U.S. ní Nàìjíríà gbà. Ugbodaga-Ngu ti di ọ̀pọ̀lọpọl ipò mú, ó ti ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí akékọ̀ọ́ ilé-ẹ̀kọ́ gíga tó sì tú ní studio rẹ̀. Ó tún ṣịṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí i olùdámọ̀ràn ìlú lásìkò FESTAC ní ọdún 1975, ó sì padà di olùkọ́ ní University of Benin.[3][4][5][6]

Ugbodaga-Ngu ṣaláìsí ní ọdún1996.[1]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 "Clara Ugbodaga-Ngu, Abstract (1960)". University of Birmingham (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-10-04. 
  2. Babah, Chinedu (2017-02-03). "NGU Etso Ugbodaga". Biographical Legacy and Research Foundation (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-10-04. 
  3. James, Sule Ameh (2023-07-26). "Clara Etso Ugbodaga-Ngu's Many Roles in Nigeria's Modernist Art Scene". post (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-10-04. 
  4. "Bonhams : Clara Etso Ugbodaga-Ngu (Nigerian, 1921-1996) Dancers". www.bonhams.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-10-04. 
  5. "Rare work by the African artist Clara Etso Ugodaga-Ngu comes to Bonhams". South African Art Times (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-02-24. Retrieved 2023-10-04. 
  6. "Artwork by Clara Etso Ugbodaga-Ngu, Dancers, Made of oil on board in 2023 | Dancer, Snapshots, Sale artwork". Pinterest (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-10-04.