Eugenia Abu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Eugenia Abu
Ọjọ́ìbíEugenia Jummai Amodu
19 Oṣù Kẹ̀wá 1962 (1962-10-19) (ọmọ ọdún 61)
Zaria, Nigeria
Iléẹ̀kọ́ gígaCity, University of London Ahmadu Bello University
Iṣẹ́
  • Journalist
  • television host
Ìgbà iṣẹ́1979–present
Àwọn ọmọ6[1]

Eugenia Abu (bíi ni ọjọ́ mọ́kàndinlógún oṣù kẹwàá ọdún 1961) jẹ́ oniroyin, agbóhùnsáfẹ́fẹ́, akọ̀wé àti akéwì.[2] Òun ni atọkun ètò ìròyìn tẹ́lẹ̀ fún Nigerian Television Authority (NTA) .[3][4] Ó ṣe atọkun ètò lórí NTA fún ọdún mẹ́tàdínlọgbọn.[5]

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bíi sì ìlú Zaria ni ọdún 1962. Ó bẹ́ẹ̀rẹ̀ sì ni kọ̀wé láti ìgbà tí ó wà ní omo ọdún méje. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ ABU Staff School ní Zaria àti Queen Amina College ní Kaduna fún ẹ̀kọ́ ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Ahmadu Bello University ní Zaria, ó sì gboyè nínú ẹ̀kọ́ èdè gẹ̀ẹ́sì ni ọdún 1981.[6] Ó gboyè Masters rẹ nínú ìmọ̀ ibaraenisoro ni Ilé ẹ̀kọ́ gíga tí University of London ni ọdún 1992. Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ USIS, ó sì ti gbà owó iranlọwọ lati ọdọ Chevening Scholarship. Ó dá ẹgbẹ́ tí àwọn ọmọdé láti ọmọ ọdún méje sì mẹẹdogun tí má kàwé ni ọdún 2018.[7] Abu jẹ́ onkọ̀we àti akéwì. Ìwé rẹ̀, In the Blink of an Eye jẹ́ kí ó gba ẹ̀bùn akọ̀wé bìnrin tó tayọ julọ ni ọdún 2008.[8][9]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]