Jump to content

Eugenia reinwardtiana

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Taxonomy not available for Eugenia; please create it automated assistant
Eugenia reinwardtiana
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ edit ]
Irú:
Template:Taxonomy/EugeniaE. reinwardtiana
Ìfúnlórúkọ méjì
Template:Taxonomy/EugeniaEugenia reinwardtiana
Synonyms[1]

Eugenia reinwardtiana je shrubu ti igi kekere kan ninu ìdílé Myrtaceae. O tan mo igbo tropical ni northern Queensland, Indonesia,[2] ati Pacific Islands, àwọn orúkọ ti a mo sí ni Cedar Bay Cherry, Beach Cherry, Australian Beach, Mountain Stopper,[3][4] Nioi (Hawaiian),[5] ati A'abang (Chamorro). Won je iwon 2 to 6 m (6.6 to 19.7 ft) ni gigun.[6]

Igi yìí jé gbagbara láàrín Cedar Bay National Park ni northern Australia ati eso re ti o se je gbajumo láàrin àwọn hippies ti o ngbe be ni ọdún 1970s.

Eso yìí ni awo ewe lakọkọ,leyin náà ni o man pon sí awo osan sí awo pupa ti o tan dáadáa pẹlu ẹran ara ti o rọ ti o sì dùn pelu.[3]

Igi ti a gbin de aarin kan fún jíjẹ rẹ ati didun re ti a maan je lati owo wa,a tun lo fún olomi osan ati candies Abi nnkan ti a lo láti fi tọju nkan.Eso yìí maan je antioxidants.[7]

Igi yìí dá fun amenity horticulture ni tropics, ati wipe a maan gbin ni median strips ni Cairns. A maan fa yo lati inu eso ti o se daradara.[6]

Eso yìí lè ní aarun (Puccinia psidii).[3]

  1. "The Plant List: A Working List of All Plant Species". Retrieved February 5, 2014. 
  2. Àdàkọ:GRIN
  3. 3.0 3.1 3.2 "Cedar Bay Cherry - Eugenia reinwardtiana". www.daleysfruit.com.au. Retrieved 2020-01-10. 
  4. "Eugenia reinwardtiana (Blume) DC.". PLANTS Database. United States Department of Agriculture. Retrieved 2009-11-10. 
  5. "nioi". Hawaiian Ethnobotany Online Database. Bernice P. Bishop Museum. Archived from the original on 2008-03-28. Retrieved 2009-11-10.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  6. 6.0 6.1 Wrigley, J.W., Fagg, M., Australian Native Plants, Collins, 1986, ISBN 0-00-216575-9
  7. Sullivan, Rachel (30 April 2009). "Rainforest Fruit Power". Australian Broadcasting Corporation. 

Àdàkọ:Commonscat-inline Àdàkọ:Wikispecies-inline

Àdàkọ:Eugenia-stub