Eya Ogu (Ogu People)

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Eya Ogu (Ogu People) ti opo eniyan maa n si pe ni Egun je eya ti tedo si ipinle Eko ati Ogun lapa gusu-iwo-oorun orile-ede Naijiria. Awon eya Ogu ni oniruuru ede-adugbo bii', Thevi, Wheda, Seto, Toli, ati bee bee lo. Awon Ogu to iwon ipin meedogun (15%) ni apapo awon olugbe ipinle Eko.[1][2]

Orisun Won

Awon Eya Ogu se wa lati orile-ede atijo Dahomeh ti a mo nisinsinyi si Orile-ede Ominira Benin (Benin Republic) Itan atenudenu kan so wipe awon Ogu je Iran kan ti won se wa lati Wheda, Alatha ati Weme ti won je ilu ti o wa lorile-ede Olominira Benin leyin Ogun Dahomey ti o be sile ni senturi mejidinlogun seyin (18th century).[3] Gegebi Olusotan Mesawaku se so ninu iwe re kan, awon eya Ogu wa tedo si Badagry lati senturi meedogun (15th century) seyin nitori aabo nigba Ogun Dahomey.[4]

Awon Itokasi

  1. "Native Peoples of the World: An Encylopedia of Groups, Cultures and Contemporary Issues". Google Books. Retrieved 2019-10-03. 
  2. Onyeakagbu, Adaobi (2019-08-24). "About Badagry, the indigenous people of Lagos". Google. Retrieved 2019-10-03. 
  3. "Five Interesting Facts About The Ogus • Connect Nigeria". Connect Nigeria. 2018-04-24. Retrieved 2019-10-03. 
  4. Tolu (2019-07-02). "THINGS YOU NEED TO KNOW ABOUT THE EGUN PEOPLE". EveryEvery (in Èdè Latini). Retrieved 2019-10-03.