Ezra Pound
Appearance
Ezra Weston Loomis Pound (30 October 1885 – 1 November 1972) je akoewi ati alayewo ara Amerika okere, ati eni pataki ni ibere irinkankan aseodeoni ninu ewikiko. O je mimo fun ipa re niu igbedagba iseaworan. Lapapo mo T.S. Eliot won gba bi akoewi daada iseodeoni lede geesi.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |