Jump to content

Fàsáásí Ọlábánkẹwin (Dágunró)

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Fàsáásí Ọlábánkẹwin tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Dágunró jẹ́ òṣèré orí ìtàgé oun sinimá àgbéléwò,ọmọ bíbí ìlú ÒṣogboÌpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1]

Àwọn sinimá tí ó ti ṣe

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  • Màlúù funfun
  • Kàkà kí'lẹ̀ kú(2008)
  • Inúnibíni (2007)

Ìkìlọ̀ agba (2008) àti bẹ́ẹ̀ beẹ̀ lọ.[2]

Fàsáásí si olóògbé ni ọjọ́ Kẹtàlá oṣù Kẹfà ọdún 2019. Sílú Eko.

  1. "BREAKING: Yoruba movie actor, Fasasi 'Dagunro' Olabanke, is dead". Within Nigeria. 2019-06-13. Retrieved 2020-01-20. 
  2. "Veteran Yoruba movie actor, Fasasi Olabankewin, is dead". Premium Times Nigeria. 2019-06-13. Retrieved 2020-01-20.