Jump to content

Fúrá

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
A Fulani woman preparing fura da nono.

Fúrá jẹ́ ónjẹ́ tí a fi ọkà bàbà àti àwọn èròjà míràn ṣe tí ọ́ wọ́pọ̀ láàrín àwọn ẹ̀yà Fúlàní àti Hausa ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Niger.[1][2] Àwọn Fúlàní ni wọ́n ni ẹ̀yà ónjẹ ìbílẹ̀ yí. Wọ́n sì ma ń ṣe Fúrá dà nunù pẹ̀lú lílọ àgbàdo tàbí ọkà bàbà tí wọn yóò sì fi wa ra tí wọ́ fún láti ara màlúù pòó pọ̀ fún mi mu.[3]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Telling Stories, Making Histories - Page 66 Certainly, the making of the classic dish, fura da nono (seasoned, boiled millet balls served with sour milk), represents such a blending of food resources and styles of cuisine. This suggests that a transfer of the cuisine of fura served with sour ...
  2. African Farming and Food Processing 2005 Fura is a staple food for both Fulanis and Hausas. Wherever there is a settlement of these tribes, fura, kindrimo and nono are marketed. A number 3f the dealers of fura are women between 25 to 35 years of age without formal education.
  3. "Fura da Nono: Save yourself some money, learn how to make millet cereal". www.puls.ng.