Fọlákẹ́ Akínyẹmí
Fọlákẹ́ Akínyẹmí tí wọ́n bí lọ́jọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹta ọdún 1999 (31 March 1990) jẹ́ gbajúmọ̀ a sáré-ìjẹ fún orílẹ̀-èdè Norway, ṣùgbọ́n tí ó jẹ́ ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ Èkó ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ gbajúmọ̀ ìlúmọ̀ọ́ká eléré ìwọ̀n mítà ọgọ́rùn-ún àti igba.
Ìgbésí ayé iṣẹ́ rẹ̀ ní ìbẹ̀rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Fọlákẹ́ sí ìlú Èkó.[1] lábala àwọn ọ̀jẹ̀ wẹ́wẹ́, ó gbé ipò kẹrin nínú eré ṣíṣá ìwọ̀n mítà ọgọ́rùn-ún níbi ìdíje 2007 European Youth Olympic Festival, àti níbi ìdíje 2009 European Junior Championships. Ó gbà ipò kejì nínú eré ìje oníwọ̀n ọgọ́rùn-ún, osin gbé ipò kẹfà nínú eré ìje oníwọ̀n igba. Bákan náà, ó díje lọ́dún 2006 nínú ìdíje relay only), the 2007 European Junior Championships, àti ìdíje 2008 World Junior Championships in Athletics – Women's 100 metres nínú idije oníwọ̀n mítà ọgọ́rùn-ún àti 2008 World Junior Championships in Athletics – Women's 200 metres oníwọ̀n mítà igba, bẹ́ẹ̀ náà lọ́dún 2011 ó kópa nínú 2011 European Athletics U23 Championships – Women's 100 metres àti 2011 European Athletics U23 Championships – Women's 200 metres) oníwọ̀n mítà ọgọ́rùn-ún àti igba, ṣùgbọ́n kò pegedé fún àṣekágbá without.[2]
Fún ìdíje ipele àwọn àgbà, ó kópa nínú 2009 European Indoor Championships, 2010 World Indoor Championships, 2010 European Championships, 2012 European Championships àti 2013 European Indoor Championships láì pegedé fún àṣekágbá.[2][3] Nínú ìdíje láàárín àwọn orílẹ̀-èdè tó ti kópa gbẹ̀yìn, ó dé ìpele tó tẹ́lẹ̀ àṣekágbá nínú ìdíje Athletics at the 2013 Summer Universiade – Women's 100 metres oníwọ̀n ọgọ́rùn-ún ti 2013 Summer Universiade. Láti ìgbà náà, ó ti fẹ̀yìntì, nítorí ìfarapa.
Àwọn àkókò ìsáré rẹ̀ tó yára jù ìṣẹ́jú aaya 7.36 nínú ìdíje ìwọ̀n ọgọ́ta (60),èyí wáyé lọ́dún 2009 ní Florø; ìṣẹ́jú àáyá 11.46 nínú ìdíje oníwọ̀n ọgọ́rùn-ún mita (100),lọ́dún 2012 ni ìdíje ní Florø; àti àáyá 23.61 nínú ìdíje oníwọ̀n mita igba,lọ́dún 2010 ni Donnas, Italy.[4] She represented the clubs IL i BUL and SK Vidar before joining IK Tjalve ahead of the 2014 season,[1]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 "Folake Akinyemi til Tjalve" (in Norwegian) (PDF). Tjalvisten (11): p. 17. 2013. Archived from the original on 7 August 2017. https://web.archive.org/web/20170807194407/http://www.tjalve.no/kx/456/files/Tjalvisten/2013/Tjalvisten%202013-11.pdf. Retrieved 7 August 2017.
- ↑ 2.0 2.1 "A". Norwegian Athletics. Retrieved 7 August 2017.
- ↑ IAAF profile for Fọlákẹ́ Akínyẹmí
- ↑ "All-Athletics.com profile". Archived from the original on 2017-08-07. Retrieved 2020-11-15.