Faith Ikidi
Ìrísí
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Faith Ikidi Michael | ||
Ọjọ́ ìbí | 28 Oṣù Kejì 1987 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Port Harcourt, Nigeria | ||
Ìga | 1.72 m | ||
Playing position | Defender | ||
Club information | |||
Current club | Piteå IF | ||
Number | 14 | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
2000–2001 | Novia Queens FC | ||
2001–2004 | Bayelsa Queens FC | ||
2004–2005 | Klepp IL | ||
2004–2006 | QBIK | ||
2007 | Eskilstuna United DFF | ||
2009–2010 | Linköpings FC | 37 | (2) |
2011– | Piteå IF | 205 | (9) |
National team | |||
2004– | Nigeria women's national football team | 53 | (0) |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of 14 October 2018. † Appearances (Goals). |
Faith Ikidi jẹ obinrin agbabọọlu ilẹ Naigiria ti a bini 28, óṣu febuary ni ọdun 1987 si ilu Port Hacourt. Arabinrin naa jẹ Defender fun Super Falcons ilẹ Naigiria ati Piteà IF ni Sweden[1].
Aṣeyọri
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Ni ọdun 2006, Ikidi jẹ ọkan lara awọn Elere Naigiria ti o jẹ Awọn Afirica akọkọ lati kopa ninu ere idije swedish nibi ti wọn ti jẹ aṣoju fun QBIK[2].
- Faith ko ipa pataki ninu aṣeyọri Super Falcons ni Cup awọn Obinrin ilẹ Afirica Agbaye ni ilu Cameroun. Arabinrin naa jẹ ikan ninu awọn agba obinrin agbabọọlu ti VAVEL UK fun loruko ni ọdun 2017[3].
Itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ https://www.zgr.net/en/people/faith-ikidi-biography-fact-career-awards-net-worth-and-life-story/amp
- ↑ http://news.bbc.co.uk/sport2/hi/football/africa/4857278.stm
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2022-05-25. Retrieved 2022-05-25.