Jump to content

Fatma Ali

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Fatma Ali
Member of the Tanzanian Parliament
In office
2005–2010
ConstituencySpecial Seat
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí28 Oṣù Kẹ̀sán 1950 (1950-09-28) (ọmọ ọdún 74)
Ọmọorílẹ̀-èdèTanzanian
Ẹgbẹ́ olóṣèlúCCM

Fatma Othman Ali (tí a bí ní ọjọ́ kejìdínlógbọ̀n oṣù kẹsàn-án ọdún 1950) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ ède Tanzania tí ó fi ìgbà kan jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ ilé ìgbìmọ̀ asofin Tanzanian kẹsàn-án. Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú Chama Cha Mapinduzi.[1]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Member of the Tanzanian Parliament". Parliament of Tanzania. Archived from the original on 26 January 2014. Retrieved 19 May 2013.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)