Felicia Bassey
Ìrísí
Felicia Bassey je olóṣèlú ọmọ orilẹ-ede Nàìjíríà. O ṣiṣẹ gẹgẹbi ọmọ ẹgbẹ ti Ile-igbimọ aṣòfin Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom, ti o nsoju àgbègbè Ipinle Okobo . Bákan naa lo tun di ipo Igbákejì olori ile ìgbìmọ̀ aṣòfin ìpínlẹ̀ Akwa Ibom. [1] [2] [3]