Felicia Eze
Ìrísí
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | 27 Oṣù Kẹ̀sán 1974 | ||
Ọjọ́ aláìsí | 31 January 2012 | (ọmọ ọdún 37)||
Ibi ọjọ́aláìsí | Anambra State, Nigeria |
Felicia Eze jẹ agbabọọlu lobinrin órile ede naigiria ti a bini 27, óṣu september ni ọdun 1974. Arabinrin naa ku lẹyin aisan ranpẹ ni 31, óṣu january ni ọdun 2012 si ipinlẹ Anambra[1][2][3].
Àṣeyọri
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Felicia gẹgẹbi ọkan lara ọmọ ẹgbẹ Super Falcons gba Ami ẹyẹ Gold ni ọdun 2003 nibi gbogbó game ilẹ Afirica fun naigria, Arabinrin naa kopa ninu olympic ọdun 2004 nibi ti o ti ṣoju órilẹ ede naigiria[4][5].