Felix Ohiwerei

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Felix Ohiwerei

Felix Omoikhoje Aizobeoje Ohiwerei je onisowo omo ile Naijiria. A bí i ní 18th January, 1937 ní Owan ní ipinle Edo ní ilẹ̀ Nààjíríà. Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ ní St David’s School Arbiosi ni 1944-1946; Government School, Owerri 1947-1950, Government Secondary School, owerri 1951-1955; Nigerian College of Arts, Science and Technology 1956-1958; University College (tí ó ti di University of Ibadan) Ibadan 1958-1961; Ó dara pọ̀ mọ Nigerian Breweries ní 1962 gẹ́gẹ́ bí i manager tí ó wà lẹ́nu ìkọ́ṣẹ́. Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ó sì bẹ̀rẹ̀ síí ní ìgbéga títí tí ó fi di Chairman àti Chief Executive officer ilé-iṣẹ́ náà ní 1997. Ó di se a laja Lever Brothers Plc (tí ó di di Unilever), ó ṣe alága virgin Anline . Ó jẹ́ fellow Nigerian Marketing Association (NMA), Geographical fcuty of Nigeria, Institute of Directors àti Adverlising Practitioners of Nigeria.